Skip to content

Latest commit

 

History

History
298 lines (149 loc) · 21.7 KB

yoruba.md

File metadata and controls

298 lines (149 loc) · 21.7 KB

BBC News Yorùbá

Èyí ni bí Mohbad ṣe ní ìfarapa tó sọ ọ́ di èrò ọrùn

Ọjọ́rú, 26 Oṣù Èrèlè 2025 ní 07:12:24

Iku Mohbad ti fa ọpọ rogbodiyan ati iwọde laarin awọn ọdọ Naijiria

Wo bí o ṣe lè dá ayédèrú òògùn mọ̀ lórí igbá

Ọjọ́rú, 26 Oṣù Èrèlè 2025 ní 09:29:35

Ajọ NAFDAC ni awọn ti gbẹsẹ le tirela mẹwaa oogun ayederu laarin ọsẹ meji pere lọja Idumota l"Eko lati igba ti awon ti bẹrẹ si ni wa ibi ti wọn ti n ta oogun ayederu kaakiri Naijiria.

Èèyàn méje dèrò ẹ̀wọ̀n lórí ikú Mojisola Awesu tó jáde láyé lẹ́yìn tó bá ọkùnrin lọ ilé ìtura

Ọjọ́ Ìsẹ́gun, 25 Oṣù Èrèlè 2025 ní 17:32:12

Eeyan meje lo foju ba ile ẹjọ lori ẹsun sise iku pa Awesu, akẹkọọ to wa ni ipele aṣekagba Kwara College of Health Technology to wa ni ijọba ibilẹ Offa.

'Mo má n tọrọ oúnjẹ láti bọ́ àwọn ọmọ mi kí kẹ̀ẹ̀kẹ́ Marwa tó gbọ̀nyà nù lára mi'

Ọjọ́ Ìsẹ́gun, 25 Oṣù Èrèlè 2025 ní 09:30:43

Ẹgbẹ awọn obinrin to n wa kẹẹkẹ Marwa nipinlẹ Ondo sọrọ lori oun to gbe wọn de idi iṣẹ naa, ati awọn ipenija wọn

Bí o ṣe lè máa ka ìròyìn BBC Yorùbá lórí WhatsApp rẹ

Ọjọ́ Ajé, 24 Oṣù Èrèlè 2025 ní 13:43:55

Ni bayii, ẹ le ri iroyin yajoyajo, iroyin lori nnkan to n lọ atawọn iroyin lori iṣẹlẹ lawujọ ti BBC Yoruba ṣe akojọpọ rẹ lori foonu yin.

Wo àwọn nǹkan ìyanu mẹ́wàá táwọn èèyàn ń pín lóde ówàńbẹ̀ lásìkò yìí

Ọjọ́ Ìsẹ́gun, 25 Oṣù Èrèlè 2025 ní 14:48:28

Latijọ, awọn nnkan bii ike iṣanwọ, abọ ijẹun, ikolẹ, aṣọ inuju, iwe pélebé ati ohun to jọ mọ bẹẹ ni wọn maa n pin lode ariya wọnyi, eyi ti awọn eeyan yoo maa ri lo lọ ti wọn yoo si maa fi ranti ayẹyẹ lagbaja ti wọn lọ.

Ikùn ni mò ń gbà ṣe ìgbọ̀nsẹ̀ àti isó nítorí jẹjẹrẹ tó mú mi- Tobiloba Oluwasina

Ọjọ́ Ìsẹ́gun, 25 Oṣù Èrèlè 2025 ní 10:33:49

Jẹjẹrẹ olorukọ nla kan lo kọlu ọdọmọbinrin ẹni ọdun mọkanlelogun (21); Oluwasina Tobiloba Elizabeth, to si sọ ọ di ẹni ti ko le ṣe igbọnsẹ loju idi bii awọn eeyan yooku mọ, to jẹ inu rẹ lo n gba ṣe igbọnsẹ lọ.

Agbábọ́ọ̀lù Naijiria jábọ́ lórí àjàkẹ́ta ilé ní Uganda, ọlọ́pàá bẹ̀rẹ̀ ìwádìí nípa ikú rẹ̀

Ọjọ́ Ìsẹ́gun, 25 Oṣù Èrèlè 2025 ní 08:25:40

Ọjọ Aje, ọjọ kẹrinlelogun, oṣu Keji ọdun 2025 ni Abubakar, ọmọ ipinlẹ Sokoto, jade laye gẹgẹ bi ẹgbẹ agbabọọlu rẹ, Vipers Sports Club, Uganda, ṣe kede.

Àwọn kókó ẹ̀sùn tí El-Rufai fi kan Tinubu, èyí tó mú kó màá sọ̀kò ọ̀rọ̀ sí lórí ayélujára

Ọjọ́ Ìsẹ́gun, 25 Oṣù Èrèlè 2025 ní 12:55:00

El-Rufai ni bo tilẹ jẹ pe Aarẹ gan an lo fi orukọ rẹ ransẹ si ile igbimọ aṣofin, to si tun fi ọwọ ara rẹ yọ kuro.

Àwọn ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa ìṣèjọba Ibrahim Babangida tí ẹnu ń kùn lẹ́yìn tó ṣèwé síta

Ọjọ́ Ìsẹ́gun, 25 Oṣù Èrèlè 2025 ní 06:16:28

Awọn kan ni ipo ti Naijiria wa lonii ni ipa ọrọ aje bẹrẹ lati asiko iṣejọba Babangida ati pe oun gan an lo bẹrẹ rẹ.

Èmi àti igbákejì mi yóò sin àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ Ondo pẹ̀lú ìbẹ̀rù Ọlọ́run, òtítọ́ inú – Aiyedatiwa

Ọjọ́ Ajé, 24 Oṣù Èrèlè 2025 ní 18:01:17

Aiyedatiwa sọ pe ohun yoo gbajumọ eto igbayegbadun awọn ara ilu papa julọ awọn to ku diẹ ka to fun lawujọ.

Gómìnà Adeleke kìlọ̀ fún àwọn alága káńsù tuntun láti má yọjú sí ọ́fíísì báyìí

Ọjọ́ Ajé, 24 Oṣù Èrèlè 2025 ní 15:43:34

Adeleke ni igbeṣẹ naa se koko lati ma le fi anfani silẹ titako ofin ilẹ Naijiria.

Wọ̀nyí làwọn ohun tó sọ ''June 12'' di mánigbàgbé ní Nàìjíríà títí di òní

Ọjọ́ Ẹtì, 21 Oṣù Èrèlè 2025 ní 16:33:55

Tolori-tẹlẹmu lo dibo naa fun MKO Abiola lai ruju, gbogbo awọn ayẹbowo lo si fidi ẹ mulẹ pe Abiola lo jawe olubori.

Darapọ̀ mọ́ wa lórí WhatsApp

Ọjọ́ Ajé, 15 Oṣù Ìgbé 2024 ní 11:20:59

Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ

'Ìyàwó mi ń bẹ̀rù ìbálòpọ̀, èmi ń bẹ̀rù ikú, ó sì ṣeéṣe kí ilé mi dàrú'

Ọjọ́ Ajé, 24 Oṣù Èrèlè 2025 ní 06:11:38

Iyawo Mike ko larun HIV, ṣugbọn o maa n loogun kan ti wọn n pe orukọ rẹ PrEP ti ko ni jẹ ki obinrin naa larun HIV.

Nítorí ọjọ́ iwájú Naijiria la ṣe pa Ọgagun Vatsa, ọ̀rẹ́ mi ìgbà èwe-IBB

Ọjọ́ Àbámẹ́ta, 22 Oṣù Èrèlè 2025 ní 11:06:39

Ẹsun naa ni IBB sọ pe o foju han kedere pe Vatsa lọwọ nibẹ, ati pe oun gan-an lo sanwo fun awọn ṣọja yooku lati wa ọna ti wọn yoo fi ditẹ gba ijọba mọ oun lọwọ.

Ìdí tí a fi dìtẹ̀ gbàjọba Buhari lọ́dún 1985 - IBB sàlàyé

Ọjọ́ Àìkú, 23 Oṣù Èrèlè 2025 ní 10:17:55

Babangida sọ ninu iwe to pe akọle rẹ ni "Irinajo lẹnu iṣẹ" pe Buhari nikan lo n da ijọba ṣe.

NAHCON àti Saudi fẹnukò lórí iye èèyàn tí yóò wá láti Naijiria fún Hajj 2025

Ọjọ́ Àìkú, 23 Oṣù Èrèlè 2025 ní 12:05:57

Ọjọgbọn Abdullahi Saleh Usman, alaga ajọ NAHCON sọ fun BBC pe gbogbo nnkan to yẹ ni awọn ti ṣe bayii.

Wo iye ìgbà tí Portable ti kó sí wàhálà òfin

Ọjọ́ Àbámẹ́ta, 22 Oṣù Èrèlè 2025 ní 14:28:16

O ti tori awọn awuyewuye to n waye yii padanu awọn ode ere, ṣugbọn ariwo ko tori ẹ tan lẹyin ariwo.

Ó ṣeéṣe kí gbogbo ọmọ Naijiria má le kàn síra wọn lórí fóònù mọ́ - ATCON

Ọjọ́ Ajé, 24 Oṣù Èrèlè 2025 ní 10:26:31

Emoekpere ni ti ijọba ko ba tete gbe igbesẹ to yẹ ni kiakia, o ṣeeṣe ki oju opo ayelujara pana, ti ọpọ eeyan, ileeṣẹ ko si ni anfani lati lo oju opo naa.

PDP fìdí àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú yòókù janlẹ̀ nínú ètò ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ nípìnlẹ̀ Osun

Ọjọ́ Àìkú, 23 Oṣù Èrèlè 2025 ní 07:07:33

Àkójọpọ́ èsì ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ nípìnlẹ̀ Osun

Ǹjẹ́ ẹ ti gbọ́ nípa Kayamayo tí àwọn ọkùnrin fi ń kojú Kayamata?

Ọjọ́ Àìkú, 23 Oṣù Èrèlè 2025 ní 08:03:27

Se ẹyin ti gbọ nipa Kayamata ri, ki ni itumọ rẹ si yin, ero wo si lo maa n wa sọkan yin, tẹ ba ti gbọ orukọ yii?

A máa lo ọ̀nà míràn láti gba ìdájọ́ b'íjọba bá já wa kulẹ̀- Bàbá Yetunde tí wọ́n bá òkú rẹ̀ nílé ààfáà n'Ilorin

Ọjọ́ Àbámẹ́ta, 22 Oṣù Èrèlè 2025 ní 09:53:31

Baba Hafsat ni oun mọ pe ilu yii le ti oun ko si fẹ sọ ohun ti mọlẹbi n gbero ṣugbọn oun fẹ ki ileeṣẹ ọlọpaa ri pe wọn fun awọn ni idajọ ododo.

Ẹja gbé arákùnrin kan mì, ló bá tún pọ̀ ọ́ sílẹ̀

Ọjọ́ Ẹtì, 21 Oṣù Èrèlè 2025 ní 09:50:22

Leti okun Chilean Patagonia ni oun ati baba rẹ lọ nigba ti iṣẹlẹ naa ṣẹ.

Nítorí ọjọ́ iwájú Naijiria la ṣe pa Ọgagun Vatsa, ọ̀rẹ́ mi ìgbà èwe-IBB

Ọjọ́ Àbámẹ́ta, 22 Oṣù Èrèlè 2025 ní 11:06:39

Ẹsun naa ni IBB sọ pe o foju han kedere pe Vatsa lọwọ nibẹ, ati pe oun gan-an lo sanwo fun awọn ṣọja yooku lati wa ọna ti wọn yoo fi ditẹ gba ijọba mọ oun lọwọ.

Àwọn obìnrìn Kenya ní àwọn kò bímọ mọ́, níṣe ni wọ́n ń so ilé ọmọ wọn pa - Ìdí rèé

Ọjọ́ Ajé, 24 Oṣù Èrèlè 2025 ní 13:31:42

Ọkan ninu awọn obinrin Kenya, Nelly Naisula Sironka, sọ pe oun ko figba kankan ronu ati bimọ ri.

Àìsàn òtútù igbáàyà ló mú Pope Francis nínú ẹ̀dọ̀fóró méjèèjì

Ọjọ́ Àbámẹ́ta, 22 Oṣù Èrèlè 2025 ní 09:46:57

Pẹlu gbogbo eyi, Vatican ni Pope si wa ni erogba gida, to si n lo gbogbo asiko rẹ lojumọ lati ka iwe, sinmi ati gbigba adura.

Mi ò kú o, mi ò sí rí ẹ̀wọ̀n he rárá – Gbajúmọ̀ òṣèrè, Dele Odule figbeta lórí àwọn tó ń gbé ìròyìn ikú rẹ̀ kiri

Ọjọ́bọ, 20 Oṣù Èrèlè 2025 ní 06:51:11

Dele Odule lo sọrọ naa ninu fidio kan to di lede loju Instagram rẹ, nibi to ti bu ẹnu atẹ lu awọn kọlọrọsi to n gbe iroyin aburu kiri nipa oun.

Ajínigbé mẹ́rin pàdé ikú lọ́wọ́ ọlọ́pàá Ogun ní márosẹ̀ Eko sí Ibadan

Ọjọ́ Àbámẹ́ta, 22 Oṣù Èrèlè 2025 ní 14:32:10

CSP Omolola Odutola, Alukoro ọlọpaa Ogun to fi atẹjade iṣẹlẹ naa sita, ṣalaye pe yatọ si awọn to di oloogbe, awọn ajinigbe kan naa fara gba ọta ibọn, wọn si gbe ọta ibọn sa lọ.

Ìwádìí BBC tú àṣírí bí iléeṣẹ́ apòògùn India kan ṣe ń kó òògùn olóró Opioid wọ Nàìjíríà, Ghana àti Ivory Coast

Ọjọ́ Ẹtì, 21 Oṣù Èrèlè 2025 ní 15:00:52

Ko si orilẹede ti wọn ti faye gba tita oogun yii fun araalu, koda, o maa n ṣokunfa ki eeyan ma lee mi daadaa ati giri.

Àlàyé ohun tójú Portable rí fún wákátí mẹ́rin kó tó rí béèlì gbà, àti ẹni tó ṣe onídúró fún un rèé

Ọjọ́ Ẹtì, 21 Oṣù Èrèlè 2025 ní 10:54:17

Bi gbogbo eto beeli naa ṣe pari ni nnkan bi agogo mẹrin kọja iṣẹju mejidinlọgbọn, ni wọn mu Portable jade sita kootu, to si lọ dupẹ lọwọ adajọ to buwọ lu iwe beeli naa fun un.

Ọlọ́pàá kú sẹ́nu iṣẹ́, òkú rẹ̀ di ariwó láàrín mọ̀lẹ́bí àti iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ondo

Ọjọ́bọ, 20 Oṣù Èrèlè 2025 ní 13:12:32

Ọjọ keji ọdun keresi ni oloogbe naa kuro nile, amọ oku rẹ ni wọn gbe wale lẹyin ọyọ diẹ.

Ṣáká lara mi dá, mi ò lárùn ọpọlọ o - Portbale sọ̀rọ̀ níwájú adájọ́

Ọjọ́bọ, 20 Oṣù Èrèlè 2025 ní 11:10:46

Ọjọru to kọja ni Portable jọwọ ara rẹ fun ọlọpaa nipinlẹ Eko, ko to di pe wọn fa a le awọn ọlọpaa ipinlẹ Ogun lọwọ.

Wo ibi tí ìgbẹ́jọ́ ẹ̀sùn ìbanilórúkọjẹ́ tí Falana pe VDM dé dúró

Ọjọ́bọ, 20 Oṣù Èrèlè 2025 ní 09:32:26

Adajọ Matthias Dawodu sun igbẹjọ ọhun siwaju lẹyin to gba lẹta lati ọwọ agbẹjọro VDM, Deji Adeyanju.

Èyí lohun tí a mọ̀ nípa Tọkọ-taya tó pa ara wọn l'Ekiti àti ìdí abájọ

Ọjọ́bọ, 20 Oṣù Èrèlè 2025 ní 09:54:40

Iroyin sọ pe awọn tọkọ-tiyawo naa pa ara wọn ni.

Àbọ̀ ìpàdé láàrin Amẹrika àti Russia lórí ọ̀nà láti dá ogun pẹ̀lú Ukraine dúró rèé

Ọjọ́rú, 19 Oṣù Èrèlè 2025 ní 08:22:14

Ṣaaju ni Russia ati Amẹrika ti buwọlu adehun lati jiroro lori dida ogun naa duro.

Kí ni àdínkù ìdá mẹ́wàá tí NBS kéde pé ó bá ọ̀wọ́ngógó túmọ̀ sí?

Ọjọ́rú, 19 Oṣù Èrèlè 2025 ní 12:26:10

Àtẹ̀jáde ti NBS fi sójú òpó wọn lórí ìkànnì ayélujára X lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun, ọjọ́ Kejìdínlógún, oṣù Kejì, ọdún 2025 ní àdínkù ìdá mẹ́wàá (10.32%) ló bá ọ̀wọ́ngógó nínú oṣù Kìíní ọdún 2025.